Yorùbá fún Alakọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ (Beginners Yoruba)
Ní ìparí ẹ̀kọ́ yìí, akẹ́kọ̀ọ́ yóò ti (By the end of the course, you should be able to) :
Mọ Álúfábẹ̀tì (Know the alphabet)
Ní ìmọ̀ nípa sílébù, àmì ohùn, àti ìsòrí òrò (Gain basic knowledge of Yoruba syllables, tonal marks, and parts of speech)
Ìkíni àti bí a ṣe ń júwe ará ẹni àti ẹlòmíràn (Greet and introduce yourself and others)
Bèère, kí o sì sọ nípa ara rẹ bí orúkọ ati bóyá o ní ìyàwó tàbí ọkọ (Ask and give personal information like name, marital status)
Sọ nípa ibi tó ǹ ńgbé (Talk about where you live)
Sọ nípa iṣẹ́ (Talk about jobs)
Sọ nípa ẹbí ì rẹ (Talk about your family)
Mò nipa mọ̀lẹ́bí àti ará ni ile Yorùbá (Understand the Yoruba family system)
Lò ọjọ́ ọ̀sẹ̀ àti oṣù inú ọdún (Use days of the week and months of the year)
Lò ònkà oókan si ọgọ́rùn-ún (Use numbers 1-100)
So aago tó lù (Tell the time)
Rà oúnjẹ (Order food)
Dúnàá dúrà l’ọ́jà (Bargain in the market when shopping)
Schedule and Fees: €50 per term
Duration: 40 minutes
10-week term