Testimonials:

ÌJẸ́RÌÍ

“My Son was asked to count numbers 1 to 10 in school, and he was doing that in Yoruba and English. He is so eager to show off to his teacher that he is learning Yoruba and knows his alphabets and numbers in another language, his teacher told me they are so proud of him learning his home language”—Mrs. Eweje, Dublin

‘’I was so concerned that my kids will be out of place if we go to visit Nigeria, because they don’t understand a single word in the language. Just three months with you guys, they are greeting us in Yoruba, and understand basic sentences, although their accent still cracks me up! THANK YOU all for your hard work’’—Mrs. Olojede, Sligo.

“Wọ́n ní kí ọmọ mi ka ònkà ní ilé ẹ̀kọ́, ó sì ká ní èdè Yorùbá àti ní èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ó ní ìfẹ́ láti fihan olùkọ́ rẹ̀ pé

òhún kọ́ èdè Yorùbá áti wípé òhún mọ àwọn álífábẹ̀tì àti ònkà ní èdè míràn, olùkọ́ rẹ̀ sì ní ó dun àwọn

nínú pé ó nkọ́ ède abínibí rẹ̀”- Ìyáàfin Eweje, Dublin.

“Ó fún mi ní àìbalẹ̀ ọkàn wípé tí abá lọ ṣe àyẹ̀wò sí Nàìjìrìà àwọn ọmọ mí ma yàtọ̀ nítorí wọn kò gbọ́ ọ̀rọ̀ kan bayi ní ède Yorùbá. Pẹ̀lú oṣù mẹ́tá péré lọ́dọ̀ yín, wọ́n tí n kí wa ní ède Yorùbá, wọ́n sì ti gbọ́ àwọn ọ̀rọ̀ kékèké, bí ó tilẹ̀jẹ̀pé ìfi àmì ohùn síi wọn má n pamí lẹ́rìín. Ẹṣé fún gbogbo akitiyan yín” - Ìyáàfin Olojede, Sligo.

Previous
Previous

COURSES