
Welcome
Ẹ Káàbọ̀!
Yoruba language School is a social enterprise established in the republic of Ireland. We train individuals and groups in Yoruba language literacy. We cater to people of all proficiency- from beginners to advanced.
Yoruba language school jẹ́ áwujọ́ kékeré kán ni ìlú Ireland. A máa ń kọ olúkúlùkù àti àkójọpọ̀ ènìyàn nì ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá láti Àlákọ́bẹ̀rẹ̀ títí dé ìpele gíga.