YORÙBÁ FÚN ÌPELE KEJÌ (INTERMEDIATE YORÙBÁ)
Ní òpin kọ́ọ̀sì yìí,O gbọ́dọ̀ lè;
(By the end of this course, you should be able to:)
* Mú ìmọ̀ rẹ dàgbà nínu sílébù,àmì ohùn àti ọ̀rọ̀ ìṣe(Advance your knowledge of syllables, tonal marks, and verbs)
* Lo èdè Yorùbá fún ìbánisọ̀rọ̀ ojojúmọ́ (Use more vocabulary for daily conversations)
* Kà, kí o sì kọ ìdáhùn àyọkà àti àlọ́ àpagbè ní Yorùbá(Read and write answers to comprehension passages, including Yoruba folktales)
* Ṣàlàyé bí a ti ń sanwó fún ọjà(Explain how to pay for a fare)
* Lo owó tó pọ̀ láti sanwó ọjà(Use high amounts to deal with transactions)
* Ṣe ìbànisọ̀rọ̀ ní orí i fóònù (Make phone conversations)
* Ka ìròyìn Yorùbá BBC (Read Yoruba BBC News)
* Mọ orin àti àṣà oge síṣe ní Yorùbá (Know Yoruba music and fashion)
* Ṣàpèjúwe òfin ojú u pópó fún bí a ti ń sọdá títì (Describe traffic rules for road crossing)