YORÙBÁ FÚN ÀWON AKẸ́KỌ̀Ọ́ GÍGA (ADVANCED YORÙBÁ)
Ní òpin kọ́ọ̀sì yìí,O gbọ́dọ̀ lè;
(By the end of this course, you should be able to:)
* Mú ìmọ̀ rẹ dàgbà nínu sílébù, àmì ohùn àti ọ̀rọ̀ ìṣe (Advance your knowledge of Yoruba syllables, tonal marks, and verbs)
* Lo Yorùbá tí ó jinlẹ̀ fún ìbánisọ̀rọ̀ ojojúmọ́ ní yàrá ìkàwé tàbi ibi ìgbafẹ́ (Use more complex vocabulary for daily conversations in domestic and class settings)
* Kà kí o sì kọ ìdáhùn àyọkà àti ìtàn àtẹnudẹ́nu (Read and write answers to comprehension passages, including folktales)
* Mọ àlọ́ àpamọ̀, ìfọ̀rọ̀dárà àti eré ìdárayá (Understand riddles, puns, and games)
* Lo òwe (Use proverbs)
* Ṣe ìdápadà àtẹ̀jísẹ́ (Exchange emails)
* Tẹ̀lé èròjà oúnjẹ fún àwọn oúnjẹ àbáláyé ti Nàìjíríà (Follow a recipe for Nigerian local dishes)
* Mọ àwọn àyájọ́ mọ́nigbàgbé (Recount memorable events/occurrences)
* Sọ̀rọ̀ nípa oríṣi iṣẹ́ ṣíṣé (Talk about types of professions)