Mission Statement:

ÈRÓNGBÀ WA

"Our mission is to promote and preserve the rich heritage of the Yoruba language and culture in Ireland by providing high-quality language education and fostering a supportive learning environment. We aim to empower students of all ages and backgrounds to communicate effectively in Yoruba and develop a deep understanding and appreciation for Yoruba culture.

Èróngbà wa ni ìdàgbàsókè ati ìpamọ́ èdè àti àṣà Yorùbá ní ìlú Ireland nípa pípèsè ẹ̀kọ́ èdè tó yanrantí àti àwùjọ tí ó ṣe alátìlẹyìn fún ẹ̀kọ́. A gbèrò láti ró àwọn akékọ̀ọ́ ní agbára láti bá àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀ dáadáa ní ède Yorùbá àti láti mú ìdàgbàsókè àti ìmọ rírì fùn àṣa Yorùbá láti alákòóbẹ̀rẹ̀ títí dé akẹ́kọ̀ọ́ àgbà.

Previous
Previous

ABOUT

Next
Next

VISION