
Vision Statement:
Ọ̀RỌ̀ ÌFOJÚSÙN
Our vision is to be the leading Yoruba language school in Ireland, recognized for our excellence in teaching, cultural immersion, and community engagement. We strive to create a vibrant and inclusive learning community where students can thrive and connect with the Yoruba language and culture. Through our innovative teaching methods and comprehensive curriculum, we aim to inspire a lifelong love for Yoruba language and culture among our students
Ìfojúsùn wa ni láti jẹ́ asíwájú nínú ẹ̀kọ́ ède Yorùbá ní ìlu Ireland, eléyìí tí wọ́n dá mọ̀ fún títayọ ní kíkọ́ ẹ̀kọ́ àti gbígbé àṣà lárugẹ. A n gbìyànjú láti dá àwùjọ tí ó ka gbogbo ènìyàn kún sílè, tí akẹ́ẹ̀kọ́ sì le gbilẹ̀ nínú àsà àti ède Yorùbá. Nìpasẹ̀ àwọn ìlànà ẹ̀kọ́ tuntun àti ọ̀nà ìkẹ́kọ̀ọ́ ìmòye tí à n lò, à gbèrò láti so èso ìfé fún èdè àti àṣà Yorùbá láílàí sí ọkàn àwọn akẹ́ẹ̀kọ́ wa.